Adétórera

Sísọ síta



Ìtumọọ Adétórera

The crown is enough for loving oneself. [verification needed]



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-tó-re-ara



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown
tó - is enough for
re - love, desire
ara - body