Adérìnlóyè
Sísọ síta
Ìtumọọ Adérìnlóyè
1. The crown walks to receive honour. 2. The crown walks into honour.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-rìn-ní-oyè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crownrìn - walk
ní - in, have
oyè - honour, chieftaincy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL