Adéráyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéráyè

The crown has secured a space.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-rí-ààyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
rí - see, find
ààyè - place, space


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO