Adéolúwatóní
Sísọ síta
Ìtumọọ Adéolúwatóní
The crown of God is worth having.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-olúwa-tó-ní
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltyolúwa - lord, God
tó - suffice for, enough for
ní - to have
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO