Adénúgbà

Sísọ síta



Ìtumọọ Adénúgbà

Royalty has its time.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-ní-ùgbà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
ní - to have
ùgbà - time, season (ìgbà)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU