Adénáíyà

Sísọ síta



Ìtumọọ Adénáíyà

Royalty is unafraid.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Òtúnáíyà



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-ní-àiyà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
ní - have
àìyà - chest
n'áíyà - be bold


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Adéláyà