Adémúléró
Sísọ síta
Ìtumọọ Adémúléró
Royalty upheld the home.
Àwọn àlàyé mìíràn
See: Oyèmúléro, Ọlámúléró, etc
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-mú-ilé-ró
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltymú - hold
ilé - house, home
ró - stand (dúró)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL