Adémúàgún
Sísọ síta
Ìtumọọ Adémúàgún
Royalty makes company/celebration perfect.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-mú-ùà-gún
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltymú - to use; to hold (onto); to make, to bring, select
ùà - the society, a gathering, celebration; royal courtyard
gún - set, to align, to be good.
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI