Adémilékan

Sísọ síta



Ìtumọọ Adémilékan

My crown has increased by one.



Àwọn àlàyé mìíràn

See: Ọlámilékan



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-mi-lé-ọ̀kan



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
mi - me
- increase by
ọ̀kan - one


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKO



Irúurú

Lékan