Adémidọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Adémidọlá

My crown has become prestige.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-mi-di-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
mi - mine
di - become
ọlá - prestige, respect


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKO
IFE



Irúurú

Dọlá