Adémidọ̀tun

Sísọ síta



Ìtumọọ Adémidọ̀tun

My royalty is renewed.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-mi-di-ọ̀tun



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
mi - mine
dì - become
ọ̀tun - renewed


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL