Adémókùn
Sísọ síta
Ìtumọọ Adémókùn
The crown has grabbed onto wealth.
Àwọn àlàyé mìíràn
Perhaps a contraction of Adémókùnọlà
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-mú-okùn-ọlà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltymú - to use; to hold (onto)
okùn - rope, thread, wealth
ọlà - prominence, riches, wealth
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI