Adélògbà

Sísọ síta



Ìtumọọ Adélògbà

The crown has enjoyed its time.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-lò-ìgbà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
- use, make us of, utilize, enjoy
ìgbà - time, season


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO