Adékúnlé

Sísọ síta



Ìtumọọ Adékúnlé

1. The crown fills the house. 2. We have arrived to fill the house.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-kún-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown
kún - fill
ilé - house, home
-
a - we
dé - arrive, return
kún - fill
ilé - house, home


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • 1. Adékúnlé Ajáṣin (Nigerian politician) 2. Emmanuel Adékúnlé Bishop of Ẹ̀gbá Anglican Diocese 3.Adékúnlé Lawal (former military governor of Lagos State)



Ibi tí a ti lè kà síi



Irúurú

Kúnlé

Dékúnlé