Adékàmíyẹ

Sísọ síta



Ìtumọọ Adékàmíyẹ

Royalty counts me worthy.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-kà-mí-yẹ



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
- read, count, consider
- me
yẹ - be respectable, be befitting of


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Kàmíyẹ