Adégúnjú

Sísọ síta



Ìtumọọ Adégúnjú

Royalty is properly set.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-gún-(ní)-ojú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ade - crown, royalty
gún - be set, be well-aligned
ní - in, at
ojú - face


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL