Adégbẹ̀gi
Sísọ síta
Ìtumọọ Adégbẹ̀gi
Royalty receives company. 2. Royalty receives honour.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-gba-ẹ̀gi
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltygba - to collect, to receive, to take
ẹ̀gi - companion, company, sibling
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OWO