Adéfugàbí
Sísọ síta
Ìtumọọ Adéfugàbí
A child born into the royal throne.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-fi-ugà-bí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltyfi - used
ugà - throne (igà)
bí - give birth to
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL