Adéfaratì

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéfaratì

What the crown rests on.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-fi-ara-tì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown
fi - use
ara - body
tì - rest on