Adéfọlátọ̀míwá
Sísọ síta
Ìtumọọ Adéfọlátọ̀míwá
The crown used honor to come and find me
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-fi-ọlá-tọ̀...mí-wá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - royalty, crownfi - used
ọlá - honor, success, wealth
tọ̀...mí - to seek out
wá - to find, to come
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL