Adéfọlálù

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéfọlálù

One hit by royal luxury.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-fi-ọlá-lù



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
fi - use
ọlá - wealth, nobility, success
- beat (drums)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Fọlálù