Adéfọlákúnmi

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéfọlákúnmi

Royalty added honour to me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-fi-ọlá-kún-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
fi - use
ọlá - prominence, prestige, wealth, honour
kún - in addition to, fulfillment
mi - me, mine


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Adéfọlá

Fọlákúnmi

Kúnmi