Adéfọlákẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéfọlákẹ́

Cherished by the crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-fi-ọlá-kẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
fi - use
ọlá - success, nobility, wealth
kẹ́ - cherish, care for


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IFE



Irúurú

Défọlákẹ́

Fọlákẹ́