Adéfọlájù

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéfọlájù

The crown is greater because of wealth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ade-fi-ọlá-jù



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown
fi - use
ọlá - wealth
jù - surpass, bigger than