Adéèjímitẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Adéèjímitẹ́
Royalty/The Crown will not let me be put to shame.
Àwọn àlàyé mìíràn
It is a condensed derivative from the statement, "Adé kò ní jẹ́ kí èmi ó tẹ́"
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-è-jẹ́-mi-tẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltyè - does not, will not
jẹ́ - let
mi - me
tẹ́ - be scorned, be put to shame
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE