Adédèjì
Sísọ síta
Ìtumọọ Adédèjì
The crown has become two.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-di-èjì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltydi - become
èjì - two, double
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Adébàyò Adédèjì (Nigerian politician) Yínká Adédèjì (Nigerian footballer) Adédèjì Òshílàjà (English footballer) Ọlámidé Adédèjì(Singer) Prof Adédèjì Ṣẹ́gun Olúgbénga(Lecturer)