Adédàmọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Adédàmọ́lá

Royalty has joined up with prestige/success/nobility.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-dà-mọ́-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown
dà - mix
mọ́ - add to
ọlá - wealth, success, nobility, prestige, honour


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • Prince (Barrister) Adédàmọ́lá Adérèmí Chief Táíwò Adédàmọ́lá Harold Ṣódípò



Ibi tí a ti lè kà síi



Irúurú

Dàmọ́lá