Adébùkọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Adébùkọ́lá

Royalty is added to affluence.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-bù-kún-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown
bù - scoop
kún - add to
ọlá - wealth, success, notability


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Irúurú

Adébùkọ́nlá

Bùkọ́la

Bùkọ́nlá

Búkì