Adébọ̀wálé
Sísọ síta
Ìtumọọ Adébọ̀wálé
The crown returned home.
Àwọn àlàyé mìíràn
"My middle name "Adébọ̀wálé" was chosen to commemorate the crowning of the new Àyàngbúrẹ̀n of Ìkòròdú in the year that I was born. The chosen Ọba Salaudeen Oyèfùsì (Ògúntádé II) was from my family and remained King for 44yrs until his death in 2014 aged 83yrs" - User commentary
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-bọ̀-wá-ilé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crownbọ̀ - return, come back
wá - come, arrive
ilé - house
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKO
GENERAL