Adéṣínà

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéṣínà

The crown opened the way.



Àwọn àlàyé mìíràn

A name given to a child born after a long period of barrenness.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-ṣí-ọnà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown
sí - open
ọ̀nà - road, lane, way, path


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Adéṣínà

Adéshínà

Ṣínà

Shínà