Adéṣẹ̀san

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéṣẹ̀san

1. The crown has made a replacement. 2. The crown has revenged.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-ṣe-ẹ̀san



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
ṣe - make, create (something good)
ẹ̀san - vengeance, reward, payback, recompense


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ṣẹ̀san