Adáralẹ́wà

Sísọ síta



Ìtumọọ Adáralẹ́wà

A prominently beautiful/handsome person.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-dára-ní-ẹwà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who (is)
dára - fine, remarkable
ní - in
ẹwà - beauty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL