Adàránboríìyàwó

Sísọ síta



Ìtumọọ Adàránboríìyàwó

One who covers their wife's head with velvet.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-da-àrán-boo-orí-ìyàwó



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
dà...bò - spread over, cover with
àrán - velvet, expensive clothing
ìyàwó - wife


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Adàrán