Adìyẹlógùn
Sísọ síta
Ìtumọọ Adìyẹlógùn
A chicken (used as a sacrifice) has supernatural power. [verification needed]
Àwọn àlàyé mìíràn
A nickname for a warrior, perhaps derived from a nickname for a warrior who used a chicken as a sacrifice and was later successful in battle.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adìyẹ-ní-oògùn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adìyẹ - chickenní - have
oògùn - drugs, medicine, supernatural intervention
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU