Adéyẹni

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéyẹni

The crown is befitting of one.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-yẹ-ẹni



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
yẹ - be respectable, be befitting of
ẹni - someone, person


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Yẹni