Adéyẹba
Sísọ síta
Ìtumọọ Adéyẹba
1. The crown befits the king. 2. The one who arrived and befits the king.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-yẹ-ọba, a-dé-yẹ-ọba
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltyyẹ - to befit, to suit me, to be worthy of
ọba - king; Ọbalúayé, the god of disease and healing
a - one who
dé - arrive
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE
OYO