Adétúnbíṣe
Sísọ síta
Ìtumọọ Adétúnbíṣe
Crown repairs pedigree.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-tún...ṣe-ìbí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltytún...ṣe - fixes, repair
ìbí - (good) birth, pedigree, family
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IBADAN