Adétẹ́níọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Adétẹ́níọlá

The crown has laid down a mat of honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-tẹ́-ẹní-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
tẹ́ - spread
ẹní - carpet, mat, rug
ọlá - wealth, honor, success


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Tẹ́níọlá