Adésùnlọ́rọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Adésùnlọ́rọ̀

The crown rests on riches.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-sùn-lé-ọrọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown
sùn - sleep, rest, rely
- on
ọrọ̀ - wealth, riches


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Désùnlọ́rọ̀