Adésẹ̀ghà

Sísọ síta



Ìtumọọ Adésẹ̀ghà

The crown has enlarged the family.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-sẹ̀-ẹ̀ghà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
sẹ̀ - to widen
ẹ̀ghà - a gathering, a group of people, community


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Sẹ̀ghà