Adérúkùọlá
Sísọ síta
Ìtumọọ Adérúkùọlá
The crown opens the door to honor; Royalty opens the door to honor.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-rú-ẹ̀kù-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltyrú - make
ẹ̀kù - door (ìlẹ̀kùn)
ọlá - wealth, nobility, prestige
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI