Adépẹ̀hìn

Sísọ síta



Ìtumọọ Adépẹ̀hìn

The crown called to those behind.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-pe-ẹ̀hìn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
pe - call
ẹ̀hìn - back, behind, legacy


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Irúurú

Adépẹ̀yìn

Dépẹ̀hìn