Adénibúyàn
Sísọ síta
Ìtumọọ Adénibúyàn
It is crown that the spirit of the deep waters has chosen (to lead).
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Fánibúyàn
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-ni-ibú-yàn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltyni - is
ibú - deep (ocean)
yàn - choose
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL