Adénítàn

Sísọ síta



Ìtumọọ Adénítàn

The crown has history.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-ní-ìtàn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
- have
ìtàn - stories, history


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ILESHA