Adémẹ̀ṣọ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Adémẹ̀ṣọ́

The crown knows beauty/adornments.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-mọ-ẹ̀ṣọ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown
mọ - know
ẹ̀ṣọ́ - guard (ọ̀ṣọ́/ẹ̀ṣọ́), protector, warrior, adornment


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL