Adélàbákẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Adélàbákẹ́
The crown is worth cherishing.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-ni-à-bá-kẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltyni - is
à - we
bá - should, ought to
kẹ́ - cherish, care for, pet
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL