Adékahùnsí
Sísọ síta
Ìtumọọ Adékahùnsí
The crown considered our voice.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-ka-ohùn-síi
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltyka - to consider, to respect
ohùn - voice
síi - to it
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI