Adékúnmi

Sísọ síta



Ìtumọọ Adékúnmi

1. Royalty complements me. 2. One who arrives to complement me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-kún-mi, a-dé-kún-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
kún - fill, add to
mi - me
-
a - someone
dé - arrive
kún - add to, fill
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Kúnmi