Adékẹ́nù
Sísọ síta
Ìtumọọ Adékẹ́nù
The crown did not waste its care (on this child). [verification needed]
Àwọn àlàyé mìíràn
See Oyèkẹ́nù, Okùkẹ́nù
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-è-kẹ́-nù
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - royalty, crownè - did not
kẹ́ - to take care of, to pamper
nù - to lose
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU