Adéfowókẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Adéfowókẹ́
Crown used money to take care (of this child).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-fi-owó-kẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crownfi - use
owó - money
kẹ́ - cherish, care for, pet, pamper
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU